Description
Lay summary for the research article published under the DOI: 10.1007/978-3-030-36540-0_72
This is Yoruba translation of DOI: DOI: 10.1007/978-3-030-36540-0_72
Àìnímọ̀ lóríi ohun ọrọ̀ ajẹ́ inú ilẹ̀ àti ìmọ̀ wọn ní Mn oje jẹ́ ìdojúkọ nínú ìṣẹ̀dáa fẹ́rómágámíìsì alọ̀ì.
Ipò ìdún, tó jẹ́ ìfọ́ká pátíkù nígbà ìgbóná, jẹ́ ìwọn pàtàkì fún mágámíìsì oje ti a kò tí kọ́ ẹ̀kọ́ nípa dáada.
Iṣẹ́ yìí yóò ṣe ìwádìí ìmọ ìṣe nípa oríṣiríṣi odìnwọn lóríi ìdún nígbà tí àwọn ore náà bá jẹ́ èyí tí a dáná ránpẹ́ sí nih ilànà òbìrìyípo.
Àwọn òdinwọn yìí jẹ́ ìyípo eré, ipò ìgbóná, ìgbóná, àti àtòpọ ohun ọrọ̀ ajé inú ilẹ̀.
Ore Soth Africa méta, méjì láti inú ìwàlẹ̀ kannáà, yóò di lílò fún iṣẹ́ ìwádìí yìí.
Ìdí ìwé kíkọ yìí ni láti ṣe ìjábọ̀ àwọn ìlànà ìdàgbàsókè.
Àwọn olùṣèwádìí ti dábàá ìwádìí tuntun láti ṣe ìdáhùn ìbéèrè nípa èròjà mágámíìsì tí a wà ni South Africa.
Àwọn olùṣèwádìí ti dábàá ìwádìí tuntun láti wá ipò iná ìléru tí ó lè ṣe àpapín mágámíìsì nígbà tí a ń ṣẹ̀dá irin.
Ìgbésẹ̀ pàtàkì nípa irin ṣíṣe ni láti ya mágámíìsì kúrò lára oje nípa fífi jó eérú-iná-ìléru.
Nígbà tí mágámíìsì bá ti ń súnmọ́ dídún látara ìgbọ́ná iná, tàbí kí ó máa ṣẹ́ sí wẹ́wẹ́, tó lè fa àìṣedédé ìlànà náà àti ìgbiná, nítoríi gáàsì.
Ẹ̀kọ́ yìí gbèrò ìwádìị́ tuntun láti rí àwọn ìlànà láti dín ìdún mágámíìsì kù.
Àwọn olùṣèwádìí náà dágbàá ká ṣe àyẹ̀wò èyí nípa lílo rotary kiln, irúfẹ́ iná ìléru olóbìrìyípo, láti dáná sí oje náà kí ó to wa inú iná ìléru.
Àwọn olùṣèwádìí náà ò ní lo ore láti Kalahari mágámíìsì ní South Africa, lí wọn sì ṣe àyẹ̀wò ráńpẹ́ óríi ìdún nínúu láàbù nípa lílo rotarin kiln.
Ìwádìí náà yóò ṣe ìdánwò ráńpẹ́ sí àkàsọ̀ dídún ní ìlòdì sí àkàsọ̀ olóbìrípo eré, ìgbóná, ipò ìyára-gbóná, ìwọn oje, àti ìdàpọ kẹ́míkálì oje náà.
Àwọn olùṣèwádìí náà ti ṣe ìwádìí ráńpẹ́ láti mo ipò irúfẹ́ ìgbèrò ìwádìí tí yóò mú èsì wá.
Wọ́n ṣe àwárí àwọn ohun to jọjú tó fi hàn pé tí àwọn mágámíìsì ore bá jẹ́ èyí tí a kọ́ dáná ránpẹ́ sí ní ìpele ọ̀tọ̀tọ̀ ní ìbámu pẹ̀lú àpòpọ kẹ́míkálì wọn.
This is Amharic translation of DOI: DOI: 10.1007/978-3-030-36540-0_72
This is a Zulu translation of DOI: DOI: 10.1007/978-3-030-36540-0_72
This is a Northern Sotho translation of DOI: DOI: 10.1007/978-3-030-36540-0_72
This is Hausa translation of DOI: DOI: 10.1007/978-3-030-36540-0_72
This is Luganda translation of DOI: DOI: 10.1007/978-3-030-36540-0_72